ASIWAJU tún síwájú gbogbo olùdíje
Láti o̩wó̩
Yínká Àlàbí
Ninu eto idibo abe̩le lati yan oludije du ipo Aare̩ ninu e̩gbe̩ oselu APC to pari laipe̩ yii ni Alagba Bola Ahmed Tinubu ti jawe olubori ninu ibo naa. Kekere ko̩ ni baba fi ju o̩mo̩ lo̩ ni iyato̩ to wa laarin Tinubu ati awo̩n to ku. E̩ wo esi idibo naa.
APC PRIMARY 2022
June 8, 2022
Asiwaju Tinubu 1271
Hon. Amaechi 316
Prof Oshibajo 235
Sen Ahmed Lawan 152
Gov Yahaya 47
Gov Omahi 38
Gov Ayade 37
Sen Ahmed Sani 4
Dr Onu 1
Sen Rochas 0
Mr Jack-Rich 0
Pastor Bakare 0
Mr Ikeobasi 0
Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ WASCCE tó fi ìsekúse parí ìdánwò
Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ WASCCE tó fi ìsekúse parí ìdánwò Yìnká Àlàbí O ma se o! Awo̩n ake̩ko̩o̩…