Amósù, Akpabio, Bankole, Badaru àti Boniffice ṣàtìlẹ́yìn fún Tinubu pé kó di Ààrẹ
Amósù, Akpabio ṣàtìlẹ́yìn fún Tinubu pé kó di Ààrẹ
Fẹ́mi Akínṣọlá
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ogun tẹ́lẹ̀ àti ojúgbà rẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Akwa Ibom tóun náà ti fìgbà kan jẹ́ gómìnà ìpínlẹ̀ náà, Godswill Akpabio, ti ní àwọn juwọ́ sílẹ̀ níbi ipò Ààrẹ, àwọn sì kéde àtìlẹ́yìn àwọn fún ọ̀kan nínú àwọn olùdíje nílẹ̀ ẹ Yorùbá, Aṣíwájú Bọla Ahmed Tinubu.
Idibo abele si n te siwaju.
Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ WASCCE tó fi ìsekúse parí ìdánwò
Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ WASCCE tó fi ìsekúse parí ìdánwò Yìnká Àlàbí O ma se o! Awo̩n ake̩ko̩o̩…