Home iroyin Olokada bila, igbadun pada silu Eko

Olokada bila, igbadun pada silu Eko

Alaafia ti n pada si igboro ni Ipilnle Eko bayii, latari bi ijoba Babajide Sanwo-Olu se f’ofin de awon olokada.

Awon olokada naa ni won ti so ara won di irunmole laarin ilu tele.

Bi opo won se n ran ole lowo, ni won n se janduku, ti won si n fa ijamba to n mu emi lo.

Sugbon bayii o, ijoba to so pe o to gee, ti o si fi ofin de won.
Ana ojo kinni osu kefa ni ofin naa sese sii f’ese dunle.
Opo eniyan ro pe ere ni ijoba n se ni, sugbon, lote yii, awada ko rara.
Awon agbofinro naa ko fi oro naa se awea, ti won si doju ogun ko enikenei to ba fe te ofin loju.

Nigba ti IROYIN OWURO lo kaakiri igboro lojo Iegun Tuesfay, a ri i pe nnkan senu rere.
Pakuru mo o ti awon olokada maa n se tele ti role, ti onikaluku n lo pelu alaafia.
Moto n lo geerege, eni to n f’ese rin naa si ni alaafia.
Ohun ti awon ara ilu wa n gba ni adura ni ki Olorun je ki ofn naa maa je amuse titi laelae.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ WASCCE tó fi ìsekúse parí ìdánwò

Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ WASCCE tó fi ìsekúse parí ìdánwò Yìnká Àlàbí O ma se o! Awo̩n ake̩ko̩o̩…