Home ÀKỌ̀TUN Íjọba ápápọ ni áwọn ti mu diẹ ninu ádéhun ọdun 2009 sẹ
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - May 16, 2022

Íjọba ápápọ ni áwọn ti mu diẹ ninu ádéhun ọdun 2009 sẹ

Íjọba ápápọ ni áwọn ti mu diẹ ninu ádéhun ọdun 2009 sẹ

Ọrẹ Òtítọ́jù

Ìpàdé tó wáyé láàrin ìjọba àpapọ̀ àti ẹgbẹ́ olùkọ́ ilé ẹ̀kọ́ gíga Fásitì, ASUU ní àná òde yìí ni ó forísánpọ́n lẹ́yìn tí àwọn ikọ̀ méjèèjì kúnà láti se àtúnse lórí ọ̀rọ̀ ìyansẹ́lódì tí wón gùn lé.

Ijiroro naa ni Sultan ti ile Sokoto, Sa’ad Abubakar, Aarẹ fun awọn ọmọ lẹyin kristi, Dr. Supo Ayokunle, Olori oṣiṣẹ ile ijọba, Ọjọgbon Ibrahim Gambari ati Minisita fọrọ oṣiṣẹ, Chris Nigige se oludari fun ni wọn kuuna lati pẹtu si ọkan ẹgbẹ olukọ ile ẹkọ giga Fasiti, ASUU lati dawọ iyansẹlọdi naa duro nigbati ọrọ lori i bi ijọba apapọ o sẹ mu ilẹri wọn wa si imuse ba tesiwaju.

Minisita fọrọ oṣiṣẹ, Chris Ngige ni ijọba apapọ ti gba lati mu adehu wọn pẹlu ajo ASUU wa si imusẹ, ti diẹ ninu adenu naa yoo si jẹ sise lọsẹ to n bọ.

Minisita naa ni, ọrọ lori adehun ọdun 2009 ati ọrọ owo oṣu wọn ni awọn maa yanju laipẹ
jọjọ.

” A ti fi ẹnu ko lori awọn adehu kan, ti a si ni igbagbọ pe ni oṣe to n bọ yoo wa si mumusẹ. Awọn ifenuko wa ni o jẹ nnkan iwuri fun ẹgbẹ olukọ ile ẹkọ giga Fasiti, ASUU lati dawọ duro iyansẹlọdi ti wọn gunlẹ.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ WASCCE tó fi ìsekúse parí ìdánwò

Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ WASCCE tó fi ìsekúse parí ìdánwò Yìnká Àlàbí O ma se o! Awo̩n ake̩ko̩o̩…