Home ÀKỌ̀TUN Ẹgbẹ́ Afẹ́nifére kàn sí Bọla Tinubu
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - October 22, 2021

Ẹgbẹ́ Afẹ́nifére kàn sí Bọla Tinubu

Ẹgbẹ́ Afẹ́nifére kàn sí Bọla Tinubu

Ọrẹ Òtítọ́jù

Ṣé wọ́n ní ọmọ ẹni kò ṣèdí bẹ̀rẹ̀kẹ̀tẹ̀ ká kó Ìlẹ̀kẹ̀ sí ìdí ọmọ ẹlòmíì, tẹni n tẹni.
Ẹgbẹ́ Afẹ́nifére, léyìí tí oloórí wọn, Olóyè Ayọ̀ Adésànyà, léwájú, ti ṣàbẹ̀wò ara ò le bí sí Aṣíwájú Bọla Ahmed Tinubu ní ilé rẹ̀ tó wà ní Bourdilon, nílùú Ìkòyí, níìpínlẹ̀ Èkó, ní ọjọ́ Ìṣẹ́gun ọ̀sẹ̀ yìí.

Lasiko abẹwo naa ni wọn ba Aṣiwaju yọ pe o ja ajabọ lọwọ aisan to gbe e kuro niluu fun ọpọlọpọ ọjọ yii, to si pada sile rẹ lalaafia..

Lara awọn to kọwọọrin pẹlu Baba Adesanya lọ sile Aṣaaju ẹgbẹ oṣelu APC naa ni Igbakeji olori ẹgbẹ Afẹnifẹre, Ọba Ọlaitan Ọladipọ, Oloye Ṣupọ Ṣhonibarẹ, igbakeji ọga ọlọpaa nilẹ wa tẹlẹ, Tunji Alapinni, ọmọ Oloye Adebanjọ, Ṣade, atawọn mi-in.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Kò sí nǹkan tó ṣòro tó kí ènìyàn pàdánù ọkọ….. Bimbo Oshin

Kò sí nǹkan tó ṣòro tó kí ènìyàn pàdánù ọkọ….. Bimbo Oshin Ọrẹ Òtítọ́jù Iná ọkọ,aya …