Home ÀKỌ̀TUN Ilé ẹjọ́ tú el-zakzaky àti ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - July 28, 2021

Ilé ẹjọ́ tú el-zakzaky àti ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀

Ilé ẹjọ́ tú el-zakzaky àti ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀

Fẹ́mi Akínṣọlá

Ajá tó relé ẹkùn tó bọ̀,ó tọ́ kí ayé kíi ewu.
Ilé ẹjọ́ gíga kan ní ìpínlẹ̀ Kaduna, ti dá Olóri ìjọ ẹsin Isilaamu Shia, Islamic Movement of Nigeria, Ibrahim el-zakzaky àti ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀. Àwọn méjéèjì n jẹ́jọ́ lórí ẹ̀sùn tó ní ìn ṣe pẹ̀lú dídá wàhálà sílẹ̀ láàrin ìlú, àti kíkórajọpọ̀ lọ́nà tí kò bá òfin mu. Ṣùgbọ́n àwọn ẹ̀sùn náà tí ìjọba ìpínlẹ̀ Kaduna fi kàn wọ́n, ni ilé ẹjọ́ ti dànù, tó sì pàṣẹ pé kí wọ́n ó tú wọn sílẹ̀ ní kíá..

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

IPOB láwọn ò fẹ́ àbẹ̀wò Ààrẹ Buhari sí ìpínlẹ̀ Imo

IPOB láwọn ò fẹ́ àbẹ̀wò Ààrẹ Buhari sí ìpínlẹ̀ Imo Fẹ́mi Akínṣọlá Ọ̀fọ́n àn tọ̀ sí gbẹ̀gìr…