Home ÀKỌ̀TUN Gómìnà CBN fagilé pàsí-pàrò̩ owó ní kò̩rò̩
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - July 27, 2021

Gómìnà CBN fagilé pàsí-pàrò̩ owó ní kò̩rò̩

Gómìnà CBN fagilé pàsí-pàrò̩ owó ní kò̩rò̩
Láti o̩wó̩
Yínká Àlàbí

Ogbeni Godwin Emefiele ti ile ifowo-pamo-si agba ti lodi si owo naira ati awon owo ile okeere ni pipaaro ni odo awon alagbara.
Gomina ni eleyii naa wa lara ohun ti ko je ki owo naira niyi lawujo. O ni gbogbo pasi-paaro owo gbodo maa waye ni ile ifowo-pamo-si.
Emefiele faju ro pe, ile ifowo-pamo-si to ba lodi si ofin yii maa foju wina Ofin ijoba.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

IPOB láwọn ò fẹ́ àbẹ̀wò Ààrẹ Buhari sí ìpínlẹ̀ Imo

IPOB láwọn ò fẹ́ àbẹ̀wò Ààrẹ Buhari sí ìpínlẹ̀ Imo Fẹ́mi Akínṣọlá Ọ̀fọ́n àn tọ̀ sí gbẹ̀gìr…