Home ÀKỌ̀TUN O̩wó̩ te̩ Sunday Igboho ní Cotonu
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - 6 days ago

O̩wó̩ te̩ Sunday Igboho ní Cotonu

Owe te Sunday Igboho ni kutonu
Oguna gbongbo to n ja fun eto omo Yoruba, Sunday Adeyemo ti gbogbo eniyan mo si Sunday Igboho lo ti ko sowo awon Otelemuye.
Ale ana ni Igboho ko sowo awon otelemuye ni orileede Cotonu. Eniyan o le gbon bi eni to n soo. Kutonu ni o fe gba sa lo si orileede Germany ki owo to tee.
Aaro oni ojo Isegun ni won maa fi owo sinkun ofin muu pada si Naijiria pelu afowo sowopo awon agbofinro Cotonu.
O ti n lo bii ose keta bayii ti awon Otelemuye ti n dode re leyin to won lo kaa mole ni oru ti owo ko tee sugbon ti owo te awon olutele re.
Ijoba se ileri pe gbogbo awon ti owo te yii lo maa foju ba ile ejo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ọwọ́ pálábá adigunjalè ẹlẹ́nimẹ́ta tó ja Tọpẹ Alabi lólè owó ṣégi

Ọwọ́ pálábá adigunjalè ẹlẹ́nimẹ́ta tó ja Tọpẹ Alabi lólè owó ṣégi Ọrẹ Òtítọ́jù Ọjọ́ gbogbo…