Home ÀKỌ̀TUN Ajobiewe je̩ è̩bùn o̩ko̩ bò̩gìnnì ló̩dò̩ O̩o̩ni
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - December 19, 2020

Ajobiewe je̩ è̩bùn o̩ko̩ bò̩gìnnì ló̩dò̩ O̩o̩ni

Ajobiewe je̩ è̩bùn o̩ko̩ bò̩gìnnì ló̩dò̩ O̩o̩ni

Nipa igbaruku ti odun karun-un Oba Adeyeye Eniitan OGUNWUSI (OJAJA KEJi) ati Ipade awon Oriade ni Ile OODUA , Oonirisa fi oko ayokele boginni da gbajugbaja osere ati akewi Yoruba “Ajobiewe’ lola’ Kabiesi fi n ye gbogbo ijokoo wi pe ninu oko ayokele marun-un ti awon yoo fi da awon eniyan lola gege bi ebun , Ajobiewe ni eni akoko nitori, “Ajobiewe’ maa n pan awon oriade le lopolopo. Pelu idunnu ati ayo ni Baba Ajobiewe’ fi n yira ope adaadatan niwaju OONIRISA!

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ilé ẹjọ́ tú el-zakzaky àti ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀

Ilé ẹjọ́ tú el-zakzaky àti ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Ajá tó relé ẹkùn tó bọ̀,ó tọ́ kí…