Home ÀKỌ̀TUN Ìjàm̀bá gáàsi dí òpópónà Èkó sí Ìbàdàn
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - December 16, 2020

Ìjàm̀bá gáàsi dí òpópónà Èkó sí Ìbàdàn

Ijamba gaasi di opopona Eko si Ibadan
Awon osise Julius Berger to n se opopona Eko si Ibadan lo seesi ko lu ero gaasi to wa ninu ile.
Gaasi ba bere si ni ro jade, oorun si gba gbogbo opopona kan paapaa julo Ilu Arepo.
Eyi mu ki awon agbofinro di alo ati abo gbogbo oko opopona naa.
Inu fuu aya fuu ni gbogbo awon olugbe adugbo naa wa. Opo tile wole adura ki ijamba naa ma se la ina lo.
Awon osise panapana ati awon to n da si ijamba ojiji ni won ti pawopo lati dekun gaasi to n ho soso jade ni iwaju ileese iwe iroyin PUNCH to wa ni Arepo. Koda won ti n je ki awon moto ti won da duro lati bii wakati meta maa lo diedie.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ọwọ́ pálábá adigunjalè ẹlẹ́nimẹ́ta tó ja Tọpẹ Alabi lólè owó ṣégi

Ọwọ́ pálábá adigunjalè ẹlẹ́nimẹ́ta tó ja Tọpẹ Alabi lólè owó ṣégi Ọrẹ Òtítọ́jù Ọjọ́ gbogbo…