Home ÀKỌ̀TUN Ìdìbò Amẹ́ríkà:Joe Biden ti ẹgbẹ́ òṣèlú Democrat ló ń léwájú báyìí
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - November 4, 2020

Ìdìbò Amẹ́ríkà:Joe Biden ti ẹgbẹ́ òṣèlú Democrat ló ń léwájú báyìí

Ìdìbò Amẹ́ríkà:Joe Biden ti ẹgbẹ́ òṣèlú Democrat ló ń léwájú báyìí

Fẹ́mi Akínṣọlá

Joe Biden ní Inú mi dùn sí ibi tí èsì ìdìbò dé dúró yìí
Alátakò Ààrẹ Donald Trump nínú ìdìbò tí wọ́n ń ka èsì rẹ̀ lọ́wọ́ ní Amẹ́ríkà, Joe Biden náà ti ṣọ̀rọ̀ sókè.

Ó ní gbogbo bí ó ṣe ń lọ ti tẹ́ òhun lọ́rùn báyìí.

Lọ́wọ-lọ́wọ́ Joe Biden asojú ẹgbẹ́ òṣèlú Democrats ló ń léwájú nínú èsì ìdìbò tí wọ́n ti kà báyìí pẹ̀lú ìbò okòólé nígbà àti mẹrin 224 .
Nígbà tí ti Trump ẹgbẹ́ Republican jẹ́ igba ó lé mẹ́tàlá 213

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Jàndùkú ya wọ iléeṣẹ́ rédíò Amúlùúdùn n’Íbàdàn, wọ́n ba ọ̀pọ̀ dúkìá jẹ́

Jàndùkú ya wọ iléeṣẹ́ rédíò Amúlùúdùn n’Íbàdàn, wọ́n ba ọ̀pọ̀ dúkìá jẹ́ Ọrẹ Òtítọ́jù Òkú k…