Home ÀKỌ̀TUN Èmi ò sá lo̩ ibìkankan – Tinubu
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - October 24, 2020

Èmi ò sá lo̩ ibìkankan – Tinubu

Èmi ò sá lo̩ ibìkankan – Tinubu

Yínká Àlàbí

Orisiirisii iroyin eleje lo ti n jade lati ojo Isegun ti isele Lekki ti waye.
Awon iroyin bii pe awon soja yinbon pa opo eniyan, opo eniyan fara gba ota ibon, Tinubu sa lo France, owo awon ajinigbe ti te Seyi Tinubu ati bee bee lo.
Opo fidio ni won tun gbe jade pe Tinubu n ba awon eniyan soro loju ona orileede France to sa lo.
Oni ojo kerinlelogun, osu kewaa odun yii ni Asiwaju Bola Tinubu jade soro pe oun ko kuro ni ile oun bee si ni Seyi wa legbe re nigba to n soro.
Oro pupo, iro lo n mu wa. E wo fidio naa…

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Jàndùkú ya wọ iléeṣẹ́ rédíò Amúlùúdùn n’Íbàdàn, wọ́n ba ọ̀pọ̀ dúkìá jẹ́

Jàndùkú ya wọ iléeṣẹ́ rédíò Amúlùúdùn n’Íbàdàn, wọ́n ba ọ̀pọ̀ dúkìá jẹ́ Ọrẹ Òtítọ́jù Òkú k…