Home ÀKỌ̀TUN ENDSARS kírun jímò̩ lójú títì Èkó àti Abuja
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - October 16, 2020

ENDSARS kírun jímò̩ lójú títì Èkó àti Abuja

ENDSARS kirun jimo ni Eko ati Abuja
“Aroni ko wale,Onikoyi ko sinmi ogun”. Oro iwode woorowo awon odo ti won ni ki opin de ba ajo olopaa SARS.
Won ni aseju ti wo oro awon olopaa naa. Gbogbo arowa ijoba lo n gba eti otun wole to si n gba ti osi jade.
Awon odo yii ni o ti to gee, won ni ileri ori ahon lasan ni gbogbo arowa ijoba. Inu tile tun bu won nigba ti ijoba apapo yi oruko SARS si SWAT. Won ni ti oruko ba yi pada,ko le yi iwa inu pada.
Iwode si n lo lowo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run Ọrẹ Òtítọ́jù Ayẹyẹ ọjọ́ọ̀bì à…