Home ÀKỌ̀TUN Ìyàwó Akeredolu fara pa níbi ètò ìdìbò; Iró̩ ńlá
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - October 10, 2020

Ìyàwó Akeredolu fara pa níbi ètò ìdìbò; Iró̩ ńlá

Ìyàwó Akeredolu fara pa níbi ètò ìdìbò; Iró̩ ńlá

Yínká Àlàbí

Iyawo Akeredolu fara pa nibi eto idibo: Iro nla
Eto idibo si ipo gomina n lo lowo bayii ni ipinle Ondo lonii ojo kewaa, osu kewaa odun yii. Eyi lo mun ki awon oniro gbe iroyin yajoyajo Kan jade pe iyawo gomina ipinle naa to si tun n dije du ipo gomina ni ipinle naa fara pa nibi rogbodiyan to be sile ni ipinle naa.
Ni iseju akan ni ileese telifison Channels ti sare pariwo jade pe iro nla ni iroyin naa.
Won n gbe fidio iro to jade naa leralera lati le je ki awon ara ilu mo pe iroyin iro ni, won ni rogbodiyan to waye ni ilu Asaba ni odun meji seyin bayii ni awon Kan lo imo ero komputa gbe jade ti won si fi iro tii nidii.
Ileese telifison yii toro aforiji lowo Arabinrin Betty Akeredolu fun asise yii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Jàndùkú ya wọ iléeṣẹ́ rédíò Amúlùúdùn n’Íbàdàn, wọ́n ba ọ̀pọ̀ dúkìá jẹ́

Jàndùkú ya wọ iléeṣẹ́ rédíò Amúlùúdùn n’Íbàdàn, wọ́n ba ọ̀pọ̀ dúkìá jẹ́ Ọrẹ Òtítọ́jù Òkú k…