Home ÀKỌ̀TUN Ìdùnú ń ṣubú lu ayọ̀ lágbo Obaseki l’Edo
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - September 20, 2020

Ìdùnú ń ṣubú lu ayọ̀ lágbo Obaseki l’Edo

Ìdùnú ń ṣubú lu ayọ̀ lágbo Obaseki l’Edo

Fẹ́mi Akínṣọlá

Ìbò kíkà ti bẹ̀rẹ̀ níbi ètò ìdìbò gómìnà Edo

Ọ̀pọ̀ àwọn olólùfẹ́ Obaseki ló ti gbàlù gbajó lẹ́yìn ti àwọn elétò ìdìbò ka iye ìbò tí àwọn olùdíje kọ̀ọ̀kan ní níbi àpótí ìbò Godwin Obaseki, nínú ètò ìdìbò tó n lọ lọ́wọ́ ní ìpińlẹ̀ Edo.

Gbogbo àwọn olólùfẹ́ Gómìnà náà ló n tú síta lẹ́yín ti àjọ tó ń mójú tó ìdìbò ń kéde ẹni tó jáwé olúborí níbẹ̀ ni ìdí àpótí Oredo Ward 4.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ọwọ́ pálábá adigunjalè ẹlẹ́nimẹ́ta tó ja Tọpẹ Alabi lólè owó ṣégi

Ọwọ́ pálábá adigunjalè ẹlẹ́nimẹ́ta tó ja Tọpẹ Alabi lólè owó ṣégi Ọrẹ Òtítọ́jù Ọjọ́ gbogbo…