Home ÀKỌ̀TUN Àwọn èèyàn ìpínlẹ̀ Edo ti bẹ̀rẹ̀ sí tẹ̀ẹ́ sójú ẹ̀, ẹ wo bó ṣe ń lọ
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - September 19, 2020

Àwọn èèyàn ìpínlẹ̀ Edo ti bẹ̀rẹ̀ sí tẹ̀ẹ́ sójú ẹ̀, ẹ wo bó ṣe ń lọ

Àwọn èèyàn ìpínlẹ̀ Edo ti bẹ̀rẹ̀ sí tẹ̀ẹ́ sójú ẹ̀, ẹ wo bó ṣe ń lọ

Fẹ́mi Akínṣọlá

Ìdìbò Gómìnà ní ìpínlẹ̀ Edo ti bẹ̀rẹ̀ ní pẹrẹu káàkiri ìpínlẹ̀ náà.
Nǹkan bíi aago mẹ́jọ ni ìdìbò bẹ̀rẹ̀

Àwọn olùdìbò ti ń tẹ̀ka láwọn ibùdó ìdìbò káàkiri ìpínlẹ̀ ọ̀hún.

Ó lé ní ènìyàn mẹ́wàá pẹ̀lú Gómìnà Godwin Obaseki, àti Osagie Ize-Iyamu tó ń díje dupò láti jẹ Gómìnà ìpínlẹ̀ náà.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Jàndùkú ya wọ iléeṣẹ́ rédíò Amúlùúdùn n’Íbàdàn, wọ́n ba ọ̀pọ̀ dúkìá jẹ́

Jàndùkú ya wọ iléeṣẹ́ rédíò Amúlùúdùn n’Íbàdàn, wọ́n ba ọ̀pọ̀ dúkìá jẹ́ Ọrẹ Òtítọ́jù Òkú k…