Home ÀKỌ̀TUN Ó di gbéré! Àsuntọ̀nà lẹ́ ẹ kún oge* Jimo Aliyu
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - September 17, 2020

Ó di gbéré! Àsuntọ̀nà lẹ́ ẹ kún oge* Jimo Aliyu

*Ó di gbéré! Àsuntọ̀nà lẹ́ ẹ kún oge*

Orí ló fọ́ ọ,
Gìrì ló kìí,
Ká sá à ti sọ pé ẹ̀dá kú,
Nínú gbogbo n tí ń jọmọ aráyé lógun,
Ikú nìkan ni kìí jẹ̀bi,
Kò kúkú ní fúnra rẹ̀ mú èèyàn,
Ó le rán iná,
Ó le rán omi,
Ó le rán ogun,
Ó lè rán ọ̀tẹ̀,
Ó lè rán àjàkálẹ̀ àrùn,
Ìjàǹbá nílé,
Ìjàǹbá lóko,
Ọrùn dẹ̀dẹ̀ má kánjú,
Gbogbo wa la ń bọ̀,
Àsìkò ló ṣọ̀tọ̀ọ̀tọ̀.
*Akọni ó Drogba.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run Ọrẹ Òtítọ́jù Ayẹyẹ ọjọ́ọ̀bì à…