Home ÀKỌ̀TUN Sanwo-Olu sí gbogbo ilé-ìwé l’Ekoo
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - August 29, 2020

Sanwo-Olu sí gbogbo ilé-ìwé l’Ekoo

Sanwo-Olu sí gbogbo ilé-ìwé l’Ekoo

Yínká Àlàbí

Awon agba bo, won ni “ko si ohun to ni ibere ti ko ni opin”.
Lati ipari osu keta odun 2020 yii ni gbogbo ile-iwe ti wa ni titi pa nitori ajakale arun covid-19.
Bayii, ijoba ipinle Eko ni ki gbogbo ile-iwe naa je sisi sile ki onikaluku awon akekoo maa ka iwe won lo.
Ojo kerinla osu kesan-an ni awon ile-iwe giga bii Fasiti, Poli,NCE ati awon ti won jo wa ni gbedeke kan naa maa bere idanilekoo nigba ti awon alakoobere ati girama maa bere tiwon ni ojo kokanlelogun osu kesan-an kan naa.
Gomina Sanwo-olu ni awon ojo wonyi le yi pada ti abajade to seru ba ni ba jade lati ile-ise eto ilera.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run Ọrẹ Òtítọ́jù Ayẹyẹ ọjọ́ọ̀bì à…