Home ÀKỌ̀TUN Ìjàm̀bá Bàlúù gbè̩mí ènìyàn méjì ni ìpínlè̩ Eko
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - August 28, 2020

Ìjàm̀bá Bàlúù gbè̩mí ènìyàn méjì ni ìpínlè̩ Eko

Ìjàm̀bá Bàlúù gbè̩mí ènìyàn méjì ni ìpínlè̩ Eko

Yínká Àlàbí

Ibuso Salvation ni adugbo Opebi ni ipinle Eko ni baluu ayara bi asa kan ti yonu ti o si ja lu awon eniyan meji lori, loju ese ni won je ipe Olorun. Enikan kan naa fara pa yanmo-yanmo.
Osan oni ojo kejidinlogbon, osu kejo yii ni isele buruku naa sele. Eyi si je ki opolopo obi kaya soke nigba ti won gbo isele yii nitori awon omo ile-iwe olodun kesan-an ati ikejila ti won n se idanwo.
Ki Eledua ba wa dawo aburu duro.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run Ọrẹ Òtítọ́jù Ayẹyẹ ọjọ́ọ̀bì à…