Home ÀKỌ̀TUN Ọwọ́ àwọn ọlọ́pàá tẹ àwọn afunrasí tó fipá bá ọmọ UNIBEN lòpọ̀
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - August 27, 2020

Ọwọ́ àwọn ọlọ́pàá tẹ àwọn afunrasí tó fipá bá ọmọ UNIBEN lòpọ̀

Ọwọ́ àwọn ọlọ́pàá tẹ àwọn afunrasí tó fipá bá ọmọ UNIBEN lòpọ̀
Láti ọwọ́ Yínká Àlàbí
Pelu akitiyan oga olopaa patapata, Ogbeni Mohammed Adamu to ran awon otelemuye lo si ipinle Edo latari akekoobinrin olodun kin-in-ni ti Fasiti Benin ti awon kan lo fi ipa ba lo, ti won si ran an lo si orun aremobo.
Akekoobinrin Uwaila Vera Omozuwa yii ni o lo ka iwe ni ile-ijosin Redeemed to wa ni Ihovbe ni ilu Benin ni ojo buruku naa. Awon afunrasi mefa lowo te, obinrin meji pelu okunrin merin, awon naa ni Nelson Ogbebor, Akato Valentine, Tina Samuel, Mary Ade, Nosa Osabohien ati Collins Ulegbe.
Komisona olopaa ni ipinle naa, Ogbeni Johnson Kokumo ni awon maa tu isu isele naa de isale ikoko ki awon maa baa gbe ebi fun alare. O ni pelu iwadii bayii, awon ti mo pe won fipa ba arabinrin naa lo ni, won la igi mo lori nigba ti won ba loo tan, ki o maa baa le daruko awon onise ibi naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo Ọrẹ …