Home ÀKỌ̀TUN Ọkọ àfẹ́sọ́nà fipá bá àbúrò ìyàwó àfẹ́sọ́nà lò
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - August 27, 2020

Ọkọ àfẹ́sọ́nà fipá bá àbúrò ìyàwó àfẹ́sọ́nà lò

Ipinle Niger ni isele yii ti sele nigba ti okunrin awako kan tan aburo iyawo afesona re ti ko tii ju omo odun mewaa pere lo wole, ti o si se e yanmo-yanmo.
Owo awon olopaa ipinle naa ti te onise ibi omo odun mejidinlogbon to se ose naa ni adugbo Tagina to wa ni ijoba ibile Rafi.
Ogbeni Adamu Usman ti o je komisona olopaa ni ipinle naa n salaye fun ajo akorinyin NAN pe afunrasi naa maa foju ba ile-ejo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nítorí ẹ̀sùn ìfipábánilòpọ̀, àwọn aláṣẹ Fásitì KWASU lé olùkọ́ kan dànù

Nítorí ẹ̀sùn ìfipábánilòpọ̀, àwọn aláṣẹ Fásitì KWASU lé olùkọ́ kan dànù Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn …