Home ÀKỌ̀TUN Mo rí ikú Ismaila Funtua, kí Buratai kún fún àdúrà – Primate Ayodele
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - July 22, 2020

Mo rí ikú Ismaila Funtua, kí Buratai kún fún àdúrà – Primate Ayodele

Mo rí ikú Ismaila Funtua, kí Buratai kún fún àdúrà – Primate Ayodele

Yínká Àlàbí

Ojise Olorun Primate Elijah Ayodele ti ile ijosin INRI Evangelical Spiritual Church lo salaye pe ki awon eniyan ma se ko oro oun danu.
O ni ijeeta ni oun riran si Aare Mohammadu Buhari pe won ni lati kun fun adura gidi nitori ki won maa ba padanu eniyan to sun mo won.
A ko tii ko ifa nile ti ifa fi n se ni ohun to n sele bayii nigba ti iroyin iku Oludasile iwe iroyin ti o tun je okan ninu awon agba ti orileede yii n bu yii kun je ipe Olorun.
Alagba Funtua je ana Aare ni eyi ti o mu ki awon ara ilu bere si ni ba Aare kedun.
Primate Elijah Ayodele tun kilo fun Ogagun Tukur Buratai ki o kun fun adura nitori iku ojiji.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run Ọrẹ Òtítọ́jù Ayẹyẹ ọjọ́ọ̀bì à…