Home ÀKỌ̀TUN Ìpínle̩ Edo fi tìlù tìfo̩n pàdé Oshiomole
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - July 19, 2020

Ìpínle̩ Edo fi tìlù tìfo̩n pàdé Oshiomole

Ìpínle̩ Edo fi tìlù tìfo̩n pàdé Oshiomole

Yínka Àlàbí

Yoruba bo won ni”omo buruku ko see fi fekun paje”. Eyi lo sele si awon ololufe Alaga tele fun egbe oselu APC, alagba Adams Oshiomole.
Tilu tifon ni won fo pade re ni oni ojo kokandinlogun osu yii ni ilu Benin ni ipinle Edo. Won ni ” omo eni ko ni se idi bebere ki awon lo fi ileke si idi omo elomiran”.
Eyi wa fun Oshiomole ni anfaani lati siregun fun awon ara ipinle naa. O ka gbogbo awon ise to ti se laarin odun mejo to fi je gomina ipinle naa. O wa fun awon ara ipinle naa ni ise se pe ki won toka si ise kan pere ti gomina Obaseki to wa nibe bayii se si ipinle naa.
“Ija lo de ti orin dowe”. Adams Oshiomole yii kan naa lo feyin pon Godwin Obaseki wole gege bii gomina ipinle naa ni odun merin seyin.
Ki Eledua ba won to ibo gomina to n bo ni osu kesan-an odun yii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ilé ẹjọ́ tú el-zakzaky àti ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀

Ilé ẹjọ́ tú el-zakzaky àti ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Ajá tó relé ẹkùn tó bọ̀,ó tọ́ kí…