Home ÀKỌ̀TUN Aare̩ fo̩wó̩ sí àkànse̩ ise̩ ìjo̩ba ìbílè̩ fún Keyamu
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - July 14, 2020

Aare̩ fo̩wó̩ sí àkànse̩ ise̩ ìjo̩ba ìbílè̩ fún Keyamu

Aare̩ fo̩wó̩ sí àkànse̩ ise̩ ìjo̩ba ìbílè̩ fún Keyamu

Yínká Àlàbí

Lati bii ose meloo Kan bayii ni ohun to jo bii ija agba ti n waye laarin awon ile igbimo ijoba apapo mejeeji ati ile ise igbani sise ti Agbejoro agba Festus Keyamu n dari.
Awon ile igbimo ni Keyamu koja aaye re lati maa da ise gbe sita. Paapaa julo ise ti o ni lati se pelu egberun eniyan kan, ijoba ibile kan.
Ise yii si maa kari gbogbo orileede yii. Won ni o ti po ju fun Minisita fun eto ise ati ipinle naa. Koda minisita igbani sise, Alagba Chris Ngige gan-an wa si ile igbimo asofin lati wa toro aforiji nipa iwa minisita re naa.
Bi o tile je wi pe oro naa jo opo omo Naijiria loju pe o ye ki awon mejeeji maa sise po ni, bawo ni enikan se maa gbee soke ti enikan maa faa wale.
Lonii yii ni Aare Mohammadu Buhari wa fowo ati ese sii pe ki Festus Keyamu maa te siwaju nipa akanse ise naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Okorocha ketí ikún sí ìpé làwọn fi ṣígun kàá mọ́lé mọ́lé-EFCC

Wọ́n ní Okorocha ketí ikún sí ìpé làwọn fi ṣígun kàá mọ́lé mọ́lé Ọrẹ Òtítọ́jù Àjọ tó ń gbó…