Home ÀKỌ̀TUN Ìjo̩ba àpapò̩ fò̩nà ìta han Ibrahim Magu
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - July 7, 2020

Ìjo̩ba àpapò̩ fò̩nà ìta han Ibrahim Magu

Ìjo̩ba àpapò̩ fò̩nà ìta han Ibrahim Magu

Yínká Àlàbí

Ana ojo kefa, osu keje odun yii ni ijoba apapo fowo sinkun ofin mu olori ajo EFCC to n gbogun ti awon to ba ko owo ilu je.
Magu yii ni opo ti n gbe oriyin fun pe lati igba ti ajo naa ti bere, ko tii si eni to ri awon onijibiti “Yahoo boys” mu bayii ri.
Opo awon oloselu naa lo ti gbogun ti ki o to di ana ti ijoba apapo gbee. Won si fi esun mejilelogun otooto kan an.Gege bi awon igbimo ijoba apapo ti Onidajo agba Ayo Salami je olori fun se salaye.
Iwadii to gbopan si n lo lowo bayii lori owo re ti won ni ko mo fun awon esun kan.
Orisiirisii iroyin lo si ti n lo lori gbigbae Magu naa. Awon kan ni ile to ta ni o ti se ojoro, awon kan ni ko mu okankan nibe sugbon o ta opo fun awon ojulumo re ati bee bee lo.
Lalai forogun,ijoba apapo ni ki o yera fun ipo naa ki iwadii fi pari lori re.
Awon igbimo ni ki o lo mu Agbejoro re wa,won ni ko letoo si Agbejoro ajo EFCC.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo Ọrẹ …