Home ÀKỌ̀TUN Covid-19 rá pálá wo̩ ìpínlè̩ Cross Rivers, ìpínlè̩ kan tó kù ní Naijiria
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - July 7, 2020

Covid-19 rá pálá wo̩ ìpínlè̩ Cross Rivers, ìpínlè̩ kan tó kù ní Naijiria

Covid-19- rá pálá wo̩ ìpínlè̩ Cross Rivers,ìpínlè̩ kan tó kù ní Naijiria

Yínká Àlàbí

Ajakale arun coronavirus to n ba gbogbo agbaye poo lati bii osu meloo kan seyin ma ti jarunpa wo ipinle Cross Rivers.
Ipinle yii nikan ni arun yii ko wo lati ipari osu keta to ti wo Naijiria.
Eniyan marun-un ni o ko arun naa ni oni, ni eyi to tumo si pe arun naa ti fan kale.
Bi o tile je pe awon eleto ilera ko gba pe arun naa ko si ni ipinle naa tele, sugbon gomina ibe, Ben Ayade ni ko si arun naa ni ipinle naa ati wi pe ko le wo ipinle naa nitori akitiyan awon lori arun naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn àgbà sọ pé ìjàngbọ̀n kìí nìka…