Home ÀKỌ̀TUN O̩pé̩ o! Akeredolu bó̩ nínú àjàgà covid-19
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - July 6, 2020

O̩pé̩ o! Akeredolu bó̩ nínú àjàgà covid-19

O̩pé̩ o! Akeredolu bó̩ nínú àjàgà covid-19

Yínká Àlàbí

Ajakale arun coronavirus ti n pa eni kukuru, to n pa eni giga, ti ko mo olowo yato fun talaka, ko mo oba bee ni ko mo ijoye, ko ki n ja ija elesinmesin, ko si ohun to kan an pelu eleyameya.
Ajakale ohun naa lo ko lu odidi bii gomina mejo ni orileede yi, ni eyi ti Arakunrin Rotimi Akeredolu wa ninu won. Ose to koja lo kede funra re pe ayewo oun gbe arun coronavirus jade. Gomina yii ba lo fun iwosan, o bere si ni sise ofiisi nile.
Gomina yii naa lo tun kede ni irole oni pe ki a ba oun dupe nipa esi ayewo to tun jade lonii ti o si gbee pe aisan naa ti kuro ni ago ara Gomina Akeredolu.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu

Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu Ọrẹ Òtítọ́jù Olùdíje fún i…