Home ÀKỌ̀TUN Ìdánwò WAEC máa wáyé lósù tó ń bò̩ – Minisita ètò-è̩kó̩
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - July 6, 2020

Ìdánwò WAEC máa wáyé lósù tó ń bò̩ – Minisita ètò-è̩kó̩

Ìdánwò WAEC máa wáyé lósù tó ń bò̩ – Minisita ètò-è̩kó̩

Yínká Àlàbí

Minisita fun ipinle ati eto eko, Ogbeni Emeka Nwajiuba kede ni irole oni pe pelu opolopo ipade pelu ajo WAEC. O ni awon ti fenu ko ki idanwo awon omo ile-iwe olodun kejila waye ni ojo kerin osu keji si ojo karun-un osu kesan-an odun yii.
Aanu awon omo yii ti n se opo obi, won ti kawe, kawe ti iwe gan-an ti su opo won.
Minisita eto eko wa gba awon obi nimoran to gbopan bii awo Erin, o ni ki awon obi ati oludasile ile-iwe se ipade bi awon omo yii se maa se atunyewo eko won laarin osu kan to wa laarin idanwo naa, ki won le se aseyori.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu

Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu Ọrẹ Òtítọ́jù Olùdíje fún i…