Home ÀKỌ̀TUN Táńkà epo méjì tún ko̩lu ara wo̩n ní Eko
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - July 4, 2020

Táńkà epo méjì tún ko̩lu ara wo̩n ní Eko

Táńkà epo méjì tún ko̩lu ara wo̩n ní Eko

Yínká Àlàbí

Ori lo ma tun ko awon to n rin opopona Ibadan si Eko yo ni owuro oni.
Sadede ni awon oko tanka agbepo meji tun fegbe ko lu ara won ni igba ti okan ni ki ohun koja lara ekeji.
Bi won se ko lu ara won ni epo bere si ni da si ori titi. Eyi mu ki awon panapana tete de si ibe, won si da gbogbo oko to n wo Eko ati eyi to n jade kuro ni Eko duro fun bii wakati merin.
Eyi su gbogbo awon arinrinajo opopona naa lonii. Ope to po ju ni pe Eledua ko je ki awon moto naa gbana.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu

Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu Ọrẹ Òtítọ́jù Olùdíje fún i…