Home ÀKỌ̀TUN È̩yin òsìsé̩ mi nílò àyè̩wò coronavirus kíákíá- Akeredolu
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - June 30, 2020

È̩yin òsìsé̩ mi nílò àyè̩wò coronavirus kíákíá- Akeredolu

È̩yin òsìsé̩ mi nílò àyè̩wò coronavirus kíákíá – Akeredolu

Yínká Àlàbí

Arakunrin Rotimi Akeredolu ti o je gomina ipinle Ondo lo n gba awon alabasise re niyanju ki won fi oro ti oun se arikogbon.
O ni iba lasan ni o se oun ti oun si se itoju ara laarin ojo meji pere. O ni leyin re ni awon ore gba oun nimoran lati se ayewo ajakale arun coronavirus.
Gomina naa ni “iyan jija lo n ba ore je” oun se ayewo ti esi ayewo si gbe pe oun ti ko arun naa.
O ni tii di asiko yii, oun ko tii le so ibi ti ati ona ti oun gba ko aisan naa. Alagba Akeredolu salaye yii funra re lori afefe pe ki won wo oun pe saka ni ara da. Oun ko tile ni inira kankan ni eyi ti awon onimo oyinbo ni ohun lo dara ju. Won ni ti eniyan ba tete kefin arun yii ti o si tete gbogun tii lo dara ju ki o to wo ara.
Eyi lo mu ki gomina gba awon osise re niyanju pe ki won tete lo se ayewo ara won nipa arun naa ki eni to ba nii le tete gbogun tii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo Ọrẹ …