Home ÀKỌ̀TUN Ajimo̩bi wo̩ káà ilè̩ lo̩
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - June 28, 2020

Ajimo̩bi wo̩ káà ilè̩ lo̩

Ajimobi wo kaa ile lo
Gomina ana ni ipinle Oyo, Oloye Abiola Ajimobi to salaisi ni ojo alamiisi ojo karundinlogbon osu kefa yii ni won ti sin ni ilana esin Musulumi. Aago mewaa aabo owuro oni ni gomina naa wole lo.
Chief Imam ilu Ibadan Sheikh Abdulganiy Abubarkry pelu iranlowo Alfa Sheikh Muyideen Bello ati Alhaji Kunle Sanni to je Alaga ajo awon Musulumi ni ilu Ibadan.
Gbogbo ofin covid-19 ni won tele ni adugbo Oluyole lati sin Oloogbe naa.
Abiola Ajimobi deni ile ni omo odun aadorin, oun ni gomina ipinle Oyo fun odun mejo.
Ara awon eniyan jankanjankan to won soju ti won tun seyin ni Senetor Teslim Folarin, Minisita ere idaraya Sunday Dare, Oloye Adelabu Adebayo, Oloye Kola Daisi, Kemi

Adebayo Alao-Akala, Senetor Abdulfatai Buhari, Alagba Shina Peller ati awon eniyan jankanjankan miiran.
Ki Eledua ba wa dele fun eni ire.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo Ọrẹ …