Melaye se àwo orin e̩lé̩yà fún Oshiomole
Melaye se àwo orin e̩lé̩yà fún Osiomole
Yínká Àlàbí
Tí ìyà ńlá bá gbéni sánlè̩, kéékèèké máa ń gorí rè̩ ni. Yorùbá rí kí wo̩n tó wí. Ìbè̩rè̩ ìjà ni ènìyàn máa ń mò̩, kò sí e̩ni tíí mo̩ ìpatí rè̩. Rògbòdìyàn ìpínlè̩ Edo gbá alága pátápátá fún e̩gbé̩ òsèlú APC síta.
Èyí ló mú kí ò̩kan nínú alátakò rè̩, Seneto̩ Dino Melaye gbé àwo orin e̩lé̩yà kan jáde fún un.
E̩ gbó̩ orin náà fúnra yín….
Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu
Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu Ọrẹ Òtítọ́jù Olùdíje fún i…