Obaseki gbo̩dò̩ díje dupò ní PDP – Ilé-e̩jó̩
Obaseki gbo̩dò̩ díje dupò ní PDP – Ilé-e̩jó̩
Yínká Àlàbí
Yoruba bo, won ni “aafaa soro ojo ku, to tumo si pe Olorun gbo adura oun”. IROYIN OWURO salaye losan-an pe ko si ohun ti ko le sele ki o to di ojo idibo abele egbe oselu PDP.
Ni owo irole yii kan naa ni ile-ejo miiran tun daa pe dandan ni ki Gomina Godwin Obaseki dije du ipo gomina labe egbe oselu egbe naa. Paapaa julo nigba ti awon alase egbe ti ye iwe re wo ti won lo kun oju osuwon gege bi alaale egbe awon.
Ile-ejo ni ko si Yekini ti o tun le yee moo lati ma se je ki o kopa ninu ibo abele naa.
Oro naa di “bi ikun lo loko ni bi takute ni, ipade di inu oko”.
Adédoyin ṣépè fáwọn oníròyìn nílé ẹjọ́
Adédoyin ṣépè fáwọn oníròyìn nílé ẹjọ́ Ọrẹ Òtítọ́jù Ìyàlẹ́nu ló jẹ́ fáwọn oníròyìn láàárọ̀…