Ìjo̩ba àpapo̩ gbé àlàálè̩ wíwo̩lé aké̩kò̩ó̩ fún ilé-ìgbìmò̩ asòfin
Ìjo̩ba àpapo̩ gbé àlàálè̩ wíwo̩lé aké̩kò̩ó̩ fún ilé-ìgbìmò̩ asòfin
Yínká Àlàbí
Minisita fun awon ipinle nipa eto eko, Ogbeni Chwukwuemeka Nwajiuba lo n ba awon oniroyin soro laipe yii pe, ijoba apapo ko gbagbe awon akekoo kaakiri Orileede yii. O ni awon akekoo yii ti wa nile lati ipari osu keta, ti ko si sele ri.
Minisita ni eyi naa n ko ijoba apapo lominu. O ni eyi lo mu ki ipade lorisiirisii waye lori oro awon omo naa pelu awon oluko won.
Minisita ni awon ti to gbogbo re po lo je ki awon gbee fun ile igbimo asofin nitori pe “a kii sosa lodo ki labelabe ma mo”.
Gbogbo bi awon oniroyin se n towo bo minisita lenu to ni minisita ni ki won ni suuru to po. O ni “eni ti a n gbe iyawo bo wa ba kii garun”. O ni oun ko fe so ohun ti awon oniroyin eleje naa gbe iro kiri. O ni opo iru iroyin yii ni oun ni lati lo si ori afefe lo pana re.
Minisita ni awon soo jade nigba kan pe eto ti wa bi awon akekoo olodun kefa,kesan-an ati olodun kejila se maa wole. O ni orisiirisii itukutu ni awon oniroyin gbe jade.
Minisita wa salaye pe ti awon ile-igbimo asofin ba ti pari ayewo won, ijoba apapo maa gbee jade si ori afefe.
Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu
Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu Ọrẹ Òtítọ́jù Olùdíje fún i…