Home ÀKỌ̀TUN Ìjàm̀bá iná tún se̩lè̩ ní òpópónà Ibadan sí Eko
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - June 21, 2020

Ìjàm̀bá iná tún se̩lè̩ ní òpópónà Ibadan sí Eko

Ìjàm̀bá iná tún se̩lè̩ ní òpópónà Ibadan sí Eko

Yínká Àlàbí

Ki Eledua ba wa gba isakoso opopona Ibadan si Eko pelu ijamba ina ni gbogbo igba. Eleeketa niyi ti awon tanka agbepo maa jona si adugbo kan naa.
Kara ti o wa ni ilu Ibafo ni awon tanka meji tun ti gbana. Okan gbe epo petiro nigba ti ekeji gbe afefe idana.
Ijamba ina yii gba asiko to po lowo awon panapana ki won to ri ina naa segun. Bi won se n bu omi sii ni ina n ke sii.
Ijamba ina naa gbemi eniyan, awon kan si fara pa yannayanna. Gbogbo ona ti won n tun se lowo ti ko tii pari lo tun ti baje.
Dukia awon to lepo ati awon ajagbe oko yii naa jona koja titunse.
Ki Eledua ba wa dawo le ona naa, ki O si ba wa bu ororo idunnu si okan awon ti eniyan won fara gba ninu ijamba naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ọwọ́ pálábá adigunjalè ẹlẹ́nimẹ́ta tó ja Tọpẹ Alabi lólè owó ṣégi

Ọwọ́ pálábá adigunjalè ẹlẹ́nimẹ́ta tó ja Tọpẹ Alabi lólè owó ṣégi Ọrẹ Òtítọ́jù Ọjọ́ gbogbo…