Home ÀKỌ̀TUN Akeredolu gbàse̩ àti àdúrà Ààre̩ láti tè̩ síwájú gé̩gé̩ bí gómìnà Ondo
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - June 17, 2020

Akeredolu gbàse̩ àti àdúrà Ààre̩ láti tè̩ síwájú gé̩gé̩ bí gómìnà Ondo

Akeredolu gbàse̩ àti àdúrà Ààre̩ láti tè̩ síwájú gé̩gé̩ bí gómìnà Ondo

Yínká Àlàbí

Gomina ipinle Ondo, Arakunrin Rotimi Akeredolu gba ilu Abuja lo lati foro re lo agba ninu itesiwaju gege bii gomina ipinle naa.
Akeredolu ni bi oun ti se ni odun merin seyin naa re ti oun si jawe olubori. O ni “odo to ba ti gbagbe orisun re satan lati gbe”.
Gbogbo gbomi sii, omi o too to wa ninu gomina yii pelu awon alenu loro ninu egbe ni o ti yanju ki o to di asiko yi.
Awon ara ipinle naa si tun ni ti o ba je ti ise akanse naa ni, oga ni Akeredolu nitori gbogbo awon ibi ti won ko ti reti ona ni gomina yii sise de.
Ibo gomina ipinle naa di osu kewaa odun ti wa yii ki a to mo eni ti o maa jawe olubori.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run Ọrẹ Òtítọ́jù Ayẹyẹ ọjọ́ọ̀bì à…