Home ÀKỌ̀TUN Ilé-e̩jó̩ da e̩jó̩ Oshiomole nù
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - June 16, 2020

Ilé-e̩jó̩ da e̩jó̩ Oshiomole nù

Ilé-e̩jó̩ da e̩jó̩ Oshiomole nù

Yínká Àlàbí

“Oro kanle kan baale, yoo kan jeje ni mo jokoo mi. Gbonmi-sii,omi-o-too to n lo ni ipinle Edo si n bi orisiirisii omo bayii ni ipinle naa.
Nnkan bii osu meji seyin bayii ni ile-ejo ni ilu Abuja se igbejo pe Alaga patapata egbe oselu APC lo roo kun nile fun igba die.
Eyi mu ki Oshiomole gba ile-ejo lo pe ko seese ki eniyan mefa pere yo odidi alaga orileede.
Ile-ejo miiran tun da ejo naa lonii ojo kerindinlogun osu kefa yii pe gbogbo ejo Adams Oshiomole ko lese nile.
Oni yii kan naa ni gomina ipinle naa binu fi egbe sile.
“Ibere ija ni eniyan maa n mo ko si eni to mo opin ija”.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Okorocha ketí ikún sí ìpé làwọn fi ṣígun kàá mọ́lé mọ́lé-EFCC

Wọ́n ní Okorocha ketí ikún sí ìpé làwọn fi ṣígun kàá mọ́lé mọ́lé Ọrẹ Òtítọ́jù Àjọ tó ń gbó…