Godwin Obaseki fe̩gbé̩ APC sílè̩
Godwin Obaseki fe̩gbé̩ APC sílè̩
Yínká Àlàbí
Gomina ipinle Edo, Godwin Obaseki ni oun ko se egbe APC mo. O ni nigba ti oun ti se ipade pelu ijoba apapo ti oun si ti mo ibi ti egbe fi si. O ni bayii oun le lo si ibi ti won ti n fe oun ti won si n fe bukata oun.
Obaseki ni ti o ba ya, oun maa je ki gbogbo aye mo ibi ti oun n lo.oun maa je ki aye mo egbe ti oun ti maa jade dije du ipo gomina ipinle Edo.
Gomina Obaseki nikan ko lo fi egbe oselu APC sile, igbakeji re, Philip Shuaibu pelu awon omo ile igbimo asofin die naa ni won fi egbe sile.
Okorocha ketí ikún sí ìpé làwọn fi ṣígun kàá mọ́lé mọ́lé-EFCC
Wọ́n ní Okorocha ketí ikún sí ìpé làwọn fi ṣígun kàá mọ́lé mọ́lé Ọrẹ Òtítọ́jù Àjọ tó ń gbó…