Home ÀKỌ̀TUN Se̩neto̩ Oshino̩wo̩ saláìsí láìpé̩ yìí yìí
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - June 15, 2020

Se̩neto̩ Oshino̩wo̩ saláìsí láìpé̩ yìí yìí

Se̩neto̩ Oshino̩wo̩ saláìsí láìpé̩ yìí

Yínká Àlàbí

Senetor Sikiru Oshinowo ti gbogbo eniyan mo si Pepper ti o n soju ipinle Eko ni ile igbimo asofin agba lo salaisi ni osan yii.
Ile-iwosan ijoba ipinle Eko ni Alagba naa dake si leyin aisan ajakale coronavirus to ti n baa poo lati bii ose meji seyin.
Aisan lo see wo, a ko ri ti olojo se!

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn àgbà sọ pé ìjàngbọ̀n kìí nìka…