Home ÀKỌ̀TUN Bàbá mi máa jáwé olúborí ipò Ààre̩ ló̩dún 2023 – Adamu Atiku
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - June 12, 2020

Bàbá mi máa jáwé olúborí ipò Ààre̩ ló̩dún 2023 – Adamu Atiku

Bàbá mi máa jáwé olúborí ipò Ààre̩ ló̩dún 2023 – Adamu Atiku
Yínká Àlàbí

Alhaji Atiku Abubakar ni igbakeji Aare tele ri ni orileede yii. Oun ni igbakeji Oloye Olusegun Obasanjo nigba naa.
Atiku dije du ipo Aare ni odun 1993 ni eyi ti o se ipo keta tele M K O Abiola ati Babagana Kingibe labe egbe oselu SDP.
O tun dije du ipo Aare ni odun 2007 labe egbe oselu AC sugbon ni igba ti oruko oludije jade, oruko Atiku Abubakar ko si ninu iwe INEC.
Odun 2011 ni Atiku pada si egbe PDP pelu awon gomina marun-un kan. O tun padanu ipo Aare bakan naa.
Atiku padanu ipo yii ni odun 2015 ati ni odun 2019 si owo Aare Mohammadu Buhari.
Omo Atiku ti o je komisona ni “esin kii da ni ki a ma tun un gun”, baba oun maa dije du ipo Aare ni odun 2023, o si maa jawe olubori.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ilé ẹjọ́ tú el-zakzaky àti ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀

Ilé ẹjọ́ tú el-zakzaky àti ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Ajá tó relé ẹkùn tó bọ̀,ó tọ́ kí…