Wó̩n jí ènìyàn méje gbe, wó̩n rán mó̩kànléló̩gó̩rin lo̩ òrun àpàpàdodo ní Bornu
Wó̩n jí ènìyàn méje gbe, wó̩n rán mó̩kànléló̩gó̩rin lo̩ òrun àpàpàdodo ní Bornu
Yínká Àlàbí
Ojo buruku esu gbomi mu mojumo oni ojo’ru je ni ipinle Bornu.
Awon adihamora ni won tun ya bii esu wo zowo ni ipinle Bornu ti won si tun bere si ni yinbon pa awon eniyan ilu naa bi eni pa eran.
Won ji Baale ilu naa gbe pelu awon mefa miiran nigba ti won ran mokanlelogorin lo orun apapadodo.
Awon eda buruku yii ti na papa bora ki awon ologun to de ilu naa.
Opo ile ni awon eda buruku naa dana sun nigba ti opo eran maluu ba isele naa lo.
Ki Eledua ba wa bu ororo itunu sokan awon ti awon eniyan won gbemi mi.
Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu
Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu Ọrẹ Òtítọ́jù Olùdíje fún i…