Home ÀKỌ̀TUN Ìjo̩ba àpapò̩ kéde ‘June 12’ gé̩gé̩ bí o̩jó̩ ìsinmi lé̩nu isé̩
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - June 10, 2020

Ìjo̩ba àpapò̩ kéde ‘June 12’ gé̩gé̩ bí o̩jó̩ ìsinmi lé̩nu isé̩

Ìjo̩ba àpapò̩ kéde ‘June 12’ gé̩gé̩ bí o̩jó̩ ìsinmi lé̩nu isé̩
Yínká Àlàbí

Lati odun to koja ni ijoba apapo ti yi ojo isejoba awa-ara-wa kuro ni ojo kokandinlogbon osu karun-un odun si ojo kejila osu kefa odun.
Eyi waye lati fi se iranti Oloogbe Moshood Kashimaawo Abiola ti gbogbo aye gba pe ibo ojo kejila odun 1994 ni ibo ti o dara ju ni orileede yii.
Won ni ibo naa ni ko ni ojoro ti o si lo ni irowo ati irose ju lati igba ti a ti bere oselu.
“Ko si bi a se le daruko aja ti a ko ni daruko ikoko to a fi see”. Eyi lo mu oro naa kan ijoba ologun igba naa ti Ajagunfehinti Badamosi Babangida je olori. Oun ni o da ibo naa nu bii omi isanwo.
Awon omo Naijiria faraya gidi ni igba naa ki Eledua to ba wa pero sii. Opo emi omo Naijiria lo ba isele naa lo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run Ọrẹ Òtítọ́jù Ayẹyẹ ọjọ́ọ̀bì à…