Home ÀKỌ̀TUN Olu Jacobs sì wà láàyè
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - June 9, 2020

Olu Jacobs sì wà láàyè

Olu Jacobs sì wà láàyè
Yínká Àlàbí

Agba oje ninu ere ori itage ni ede Oyinbo, Alagba Olu Jacobs ni awon iroyin eleje kan n gbee kiri lori ero ayelujara lati aaro oni pe, “olodi baba naa ti lo je ipe awon baba nla won”.
Eyi mu ki IROYIN OWURO se iwadii lori re ti abajade si fun wa ni esi to dara pe baba si wa laye koda won wa laaye.
Ibi iwadii yii naa ni o ti ta si wa leti pe baba yii saisan ranpe ni nnkan bi osu meji seyin sugbon ti won ti gbadun daadaa.
Aipe yii naa ni Alagba yii se ojo ibi odun metadinlogorin (77years) loke eepe ti awon ati gbaju-gbaja aya won, Joke Silva si n sayeye naa.
Ki Eledua ba wa lora emi Alagba Olu Jacobs.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu

Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu Ọrẹ Òtítọ́jù Olùdíje fún i…