Home ÀKỌ̀TUN Ìpínlè̩ méjìlélógún máa ní ìsòro owó osù lé̩yìn covid-19
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - June 5, 2020

Ìpínlè̩ méjìlélógún máa ní ìsòro owó osù lé̩yìn covid-19

Ìpínlè̩ méjìlélógún máa ní ìsòro owó osù lé̩yìn covid-19
Yínká Àlàbí

Yoruba bo” won ni ko si ohun to ni ibere ti ko ni opin”. Ogun covid-19 to o ti n ba gbogbo agbaye ja lati bii osu meta seyin bayii ni awon omoran tii mo oyun igbin ninu ikarahun ti kilo fun wa ki a sowo na.
Alagba Tunji Ogunyemi tenu mo o pe leyin ipinle Eko, Rivers ati awon ipinle meji miran, o maa soro fun awon ipinle mejilelogbon (32 states) lati le rowo osu san fun osise.
Alagba yii ni isiro ti ko ruju rara ni oro naa, o ni a kan n nawo ni, a ko sise fun omiran ni eyi to tumo si pe “ko le si abuja kankan lorun ope”.
Alagba Ogunyemi ni awon kan le koko bere pelu idaji owo osu sugbon to ba ya awon naa a dara po pelu awon ti ko ri san rara.
Alagba yii ni oun ko seru ba wa rara, oun kan fe ki a ni ajeseku ki a si pond sile de ongbe ni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo

Ó yẹ kí Orílẹ̀ yìí gba ọlọ́pàá síi, kí á pèsè ohun ààbò ogun tiwantiwa–Ọsinbajo Ọrẹ …