Home ÀKỌ̀TUN Gómìnà ìpínlè̩ Eko so̩ Mó̩sálási àti S̩ó̩ò̩sì di sísí
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - June 4, 2020

Gómìnà ìpínlè̩ Eko so̩ Mó̩sálási àti S̩ó̩ò̩sì di sísí

Gómìnà ìpínlè̩ Eko so̩ Mó̩sálási àti S̩ó̩ò̩sì di sísí
Yínká Àlàbí

Gomina Babajide Sanwo-olu ti ipinle Eko lo n ba awon oniroyin soro lonii pe awon ile-ijosin wa gbogbo le di Sisi’s.
O ni ki awon Mosalasi di sisi lati ojo Jimo, ojo kokandinlogun osu yii nigba ti awon Soosi maa bere isin tiwon naa lati Sonde ojo kokanlelogun osu yii.
Gomina nii awon ofin to de bi onikaluku se ma josin ti wa nitori pe orisiirisii ipade lo ti lo laarin ijoba ipinle Eko ati awon olori esin naa.
Gomina ni ile-ijosin kankan ko gbodo ni ju ero ida ogoji ninu ida ogorun-un lo. Won si gbodo tele gbogbo ilana ti ijoba fi sile bi o tile je pe awon eto alaabo ijoba naa ko ni jinna si awon ile-ijosin naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Okorocha ketí ikún sí ìpé làwọn fi ṣígun kàá mọ́lé mọ́lé-EFCC

Wọ́n ní Okorocha ketí ikún sí ìpé làwọn fi ṣígun kàá mọ́lé mọ́lé Ọrẹ Òtítọ́jù Àjọ tó ń gbó…