Home ÀKỌ̀TUN Àjàkálè̩ àrùn covid-19 sì ń pò̩ síi ní Naijiria – NCDC
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - June 4, 2020

Àjàkálè̩ àrùn covid-19 sì ń pò̩ síi ní Naijiria – NCDC

Àjàkálè̩ àrùn covid-19 sì ń pò̩ síi ní Naijiria- NCDC
Yínká Àlàbí

“Kaka ki ewe agbon de, pipele lo ma tun n pele sii”.
Ajakale arun coronavirus to ti wo orileede yii lati ipari osu keji ma ko ko lo. Bee ni awon to n ko arun naa n po sii.
Oro arun naa ti fe su awon alase ati awon ara ilu ni eyi to mu ki eto bi ise se maa bere, bi ile-ijosin se maa bere isin kaakiri ilu, bi ile-iwe se maa wole ati bee bee lo.
Eyi lo gbode Kan bayii o, bi o tile je pe, o si n ya awon eniyan kan lenu pe bawo ni ilu yii se maa n se nnkan ni atoripodi bayii.
Aropo awon to ko arun naa ti wo egberun mokanla le ni eedegbeta ati mejidinlogun (11,516). Eniyan irinajo din aadota (350) lo tun ko arun naa ni ojo kerin, osu kefa yii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn wọ̀nyí ti kékeré dèrò ẹ̀wọ̀n, jìbìtì orí ayélujára ló kó bá wọn

Àwọn wọ̀nyí ti kékeré dèrò ẹ̀wọ̀n, jìbìtì orí ayélujára ló kó bá wọn Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn ló …