Home ÀKỌ̀TUN Adigunjalè gbàjo̩ba Kogi
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - June 4, 2020

Adigunjalè gbàjo̩ba Kogi

Adigunjalè gbàjo̩ba Kogi
Yínká Àlàbí

“Ojo buruku esu gbomi mu” ni ojo Alamisi ojo kerin, osu kefa odun yii je fun awon olugbe ipinle Kogi.
Ojiji ni awon adigunjale ti won diha mora ya wo ilu Lokoja, won si koko gba ago olopaa kan lo, won pa oga olopaa (DPO) ibe pelu awon olopaa mefa miiran, koda obinrin olopaa meji wa ninu won.
Leyin eyi ni awon onise ibi naa gba ile ifowo-pamo-si agbegbe naa lo ti won tun lo da ibon bo awon ti won ba nibe, olopaa kan pelu ara ilu kan tun ba isele buruku naa lo.
Titi di asiko ti a n ko iroyin yii jo, ko tii si eni to le so iye owo ti awon eni ibi naa ko ni banki naa.
Ki Eledua ba wa dawo aburu duro,ki o si ba wa bu ororo idunnu si okan awon ti won padanu eniyan won ninu isele buruku naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run Ọrẹ Òtítọ́jù Ayẹyẹ ọjọ́ọ̀bì à…