Home ÀKỌ̀TUN O̩ló̩run ló máa fihàn mí ìgbà ti ilé-ìjó̩sìn máa di sísí – T B Joshua
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - June 3, 2020

O̩ló̩run ló máa fihàn mí ìgbà ti ilé-ìjó̩sìn máa di sísí – T B Joshua

O̩ló̩run ló máa fihàn mí ìgbà ti ilé-ìjó̩sìn máa di sísí – T B Joshua
Yínká Àlàbí

Pasito T B Joshua ti ile ijosin gbaju-gbaja Synagogue lo n salaye fun awon oniroyin pe ko tii to asiko lati si awon ile-ijosin gbogbo.
O ni ile Olorun ni awon ile-ijosin yii, Olorun naa lo si maa fihan oun ni igba ti asiko ba to.
Abajade ohun ti ijoba salaye nipa imurasile lati si awon ile ijosin wa gbogbo lo bi ohun ti Pasito Synagogue salaye yii.
O ni, oun ko tii ri rara pe asiko ti to lati si awon ile-ijosin. O ni ko si ni dara ki a ma se tele ase Olorun nitori pe aitele ase Olorun lo sun wa de ibi ti a wa yii.
Pasito salaye pe ki awon ijo oun ati awon eniyan to ba fe gbo oro Olorun si maa kan si oun ni ikanni Emmanuel TV lori DSTV.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn àgbà sọ pé ìjàngbọ̀n kìí nìka…