DSTV, sanwó ohun tí o bá lo lará ìlú ń fé̩ – Ilé ìgbìmò̩ asòfin
DSTV, sanwó ohun tí o bá lo lará ìlú ń fé̩ – Ilé ìgbìmò̩ asòfin
Yínká Àlàbí
Ile igbimo asoju-sofin ti yari kanle fun awon ile ise agbohun-gbaworan safefe (DSTV) pe, ohun ti awon ara ilu ba fe ni won gbodo ba won fe.
Won ni awon ti kilo fun won ri ni igba kan ki won lo tun ero won se ni eyi to maa da bii igba ti eniyan ba n ra si foonu re.
Ohun ti eniyan ba lo ni o maa san owo re. Alaga igbimo (ad hoc committee), Ogbeni Unyime Idem ni awon ara ilu ni awon n soju, awon si ti bi won ohun ti won fara mo ninu ohun ti won n lo bayii ati ki won maa san owo ohun ti won ba lo, won si da awon lohun pe ki awon maa san owo bi awon ba se n loo si.
Awon igbimo yii ni ko si ohun miiran to gbodo ye ife awon ara ilu yii. Eyi tumo si pe ase ti gun un, ki onikaluku to ba n lo DDTV maa reti ayipada laipe.
Adédoyin ṣépè fáwọn oníròyìn nílé ẹjọ́
Adédoyin ṣépè fáwọn oníròyìn nílé ẹjọ́ Ọrẹ Òtítọ́jù Ìyàlẹ́nu ló jẹ́ fáwọn oníròyìn láàárọ̀…