Home ÀKỌ̀TUN Sokoto pàdánù ènìyàn 74 – Tambuwar
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - May 29, 2020

Sokoto pàdánù ènìyàn 74 – Tambuwar

Sokoto pàdánù ènìyàn 74 – Tambuwar
Yínká Àlàbí

Gomina ipinle Sokoto Alhaji Aminu Tambuwar lo rowo ebe si ijoba apapo fun iranlowo.
Gomina ni osan kan oru kan ni awon adiha-moran dede gbona eburu yo si ipinle naa ti won si bere si ni se awon eniyan ilu naa bi ose se n soju.
Ni kika ni meni meji, ipinle naa ti padanu eniyan merinlelaadorin si isele buruku naa.
Eyi lo mu ki gomina sare gba ilu Abuja lo lati tete lo beere fun iranlowo ologun ati ohun ija lati koju awon eni ibi to n kogun ja ipinle naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu

Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu Ọrẹ Òtítọ́jù Olùdíje fún i…